Àwọn Ọba Kinni 13:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin kan tí wọn ń kọjá lọ rí òkú ọkunrin yìí lójú ọ̀nà, ati kinniun tí ó dúró tì í. Wọ́n lọ sí ìlú Bẹtẹli níbi tí wolii àgbàlagbà náà ń gbé, wọ́n sì ròyìn ohun tí wọ́n rí fún un.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:17-34