Àwọn Ọba Kinni 13:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Kàkà bẹ́ẹ̀, o pada, o jẹ, o sì mu ní ibi tí òun ti pàṣẹ pé o kò gbọdọ̀ fi ẹnu kan nǹkankan. Nítorí náà, o óo kú, wọn kò sì ní sin òkú rẹ sinu ibojì àwọn baba rẹ.”

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:14-32