Àwọn Ọba Kinni 13:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii àgbàlagbà, ará Bẹtẹli náà bá purọ́ fún un pé, “Wolii bíi rẹ ni èmi náà. OLUWA ni ó sì pàṣẹ fún angẹli kan tí ó sọ fún mi pé kí n mú ọ lọ sí ilé, kí n sì fún ọ ní oúnjẹ ati omi.”

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:14-25