Àwọn Ọba Kinni 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

ó bẹ̀rẹ̀ sí lépa wolii ará Juda náà. Ó bá a níbi tí ó jókòó sí lábẹ́ igi Oaku kan, ó bi í pé, ṣe òun ni wolii tí ó wá láti Juda? Ọkunrin náà sì dá a lóhùn pé òun ni.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:7-18