Àwọn Ọba Kinni 12:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeroboamu tún kọ́ àwọn pẹpẹ ìrúbọ sí orí òkè káàkiri, ó sì yan àwọn eniyan ninu gbogbo ìdílé tí kì í ṣe ìran ẹ̀yà Lefi, láti máa ṣiṣẹ́ alufaa.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:23-33