Àwọn Ọba Kinni 12:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeroboamu ọba Israẹli mọ odi yí ìlú Ṣekemu, tí ó wà ní agbègbè olókè ti Efuraimu ká, ó sì ń gbé ibẹ̀. Lẹ́yìn náà, láti Ṣekemu ó lọ mọ odi yí ìlú Penueli ká.

Àwọn Ọba Kinni 12

Àwọn Ọba Kinni 12:18-27