Àwọn Ọba Kinni 11:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn yóo ku ẹ̀yà kan sí ọwọ́ Solomoni, nítorí ti Dafidi, iranṣẹ òun, ati nítorí Jerusalẹmu, ìlú tí òun yàn fún ara òun ninu gbogbo ilẹ̀ Israẹli.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:23-40