Àwọn Ọba Kinni 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n kò ní gba gbogbo ìjọba náà kúrò lọ́wọ́ rẹ̀, n óo ṣẹ́ ẹ̀yà kan kù sí ọmọ rẹ lọ́wọ́, nítorí ti Dafidi iranṣẹ mi ati ìlú Jerusalẹmu tí mo ti yàn.”

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:9-20