Àwọn Ọba Kinni 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ àwọn obinrin àjèjì ni Solomoni fẹ́, lẹ́yìn ọmọ Farao, ọba Ijipti, tí ó kọ́kọ́ fẹ́, ó tún fẹ́ ará Moabu ati ará Amoni, ará Edomu ati ará Sidoni, ati ará Hiti.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:1-3