Àwọn Ọba Kinni 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni dáhùn gbogbo àwọn ìbéèrè rẹ̀, kò sì sí ohunkohun tí ó le fún Solomoni láti ṣàlàyé.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:1-12