Àwọn Ọba Kinni 10:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ọba mú kí fadaka pọ̀ ní Jerusalẹmu bí òkúta, igi Kedari sì pọ̀ bí igi Sikamore tí ó wà káàkiri ní Ṣefela ní ẹsẹ̀ òkè Juda.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:17-29