Àwọn Ọba Kinni 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ṣe igba (200) apata wúrà ńláńlá, wúrà tí ó lò fún ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ẹgbẹta (600) ìwọ̀n ṣekeli.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:12-17