Àwọn Ọba Kinni 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọbabinrin Ṣeba gbọ́ òkìkí ọgbọ́n Solomoni, ó wá sí Jerusalẹmu láti fi àwọn ìbéèrè tí ó takókó dán an wò.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:1-2