Àwọn Ọba Kinni 1:48 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní ‘Ìyìn ni fún OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ó jẹ́ kí ọ̀kan ninu àwọn ọmọ mi jọba lónìí, tí ó sì jẹ́ kí n fi ojú mi rí i.’ ”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:41-53