Àwọn Ọba Kinni 1:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Adonija ati gbogbo àwọn tí ó pè sí ibi àsè rẹ̀ ti ń parí àsè, wọ́n gbọ́ ariwo náà. Nígbà tí Joabu gbọ́ fèrè, ó bèèrè pé, “Kí ni ìtumọ̀ gbogbo ariwo tí wọn ń pa ninu ìlú yìí?”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:31-48