Àwọn Ọba Kinni 1:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí OLUWA ti wà pẹlu kabiyesi, bẹ́ẹ̀ náà ni kí ó wà pẹlu Solomoni, kí ó sì mú kí ìgbà tirẹ̀ tún dára ju ìgbà ti kabiyesi, oluwa mi, Dafidi ọba lọ.”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:28-40