Àwọn Ọba Kinni 1:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Batiṣeba wólẹ̀ níwájú ọba, ó dojúbolẹ̀, ó ní, “Kabiyesi, oluwa mi, kí ẹ̀mí ọba ó gùn.”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:29-33