Àwọn Ọba Kinni 1:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá búra fún un pé, “Mo ṣe ìlérí fún ọ ní orúkọ OLUWA Alààyè, tí ó gbà mí ninu gbogbo ìyọnu mi,

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:23-38