Àwọn Ọba Kinni 1:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kò pe èmi iranṣẹ rẹ sí ibi àsè náà, kò sì pe Sadoku alufaa, tabi Bẹnaya, ọmọ Jehoiada, tabi Solomoni iranṣẹ rẹ.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:23-34