Àwọn Ọba Kinni 1:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá sọ fún ọba pé Natani wolii ti dé. Nígbà tí Natani wọlé, ó wólẹ̀ níwájú ọba, ó sì dojúbolẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:17-31