Àwọn Ọba Kinni 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú rẹ ni gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ń wò báyìí, pé kí o fa ẹni tí o bá fẹ́ kí ó jọba lẹ́yìn rẹ kalẹ̀ fún wọn.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:16-22