Àwọn Ọba Kinni 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn iranṣẹ rẹ̀ wí fún un pé, “Kabiyesi, jẹ́ kí á wá ọdọmọbinrin kan fún ọ, tí yóo máa wà pẹlu rẹ, tí yóo sì máa tọ́jú rẹ. Yóo máa sùn tì ọ́ kí ara rẹ lè máa móoru.”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:1-6