Àwọn Ọba Keji 9:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu bá gbé ojú rẹ̀ sókè, ó ní, “Ta ló wà lẹ́yìn mi ninu yín?” Àwọn ìwẹ̀fà meji tabi mẹta sì yọjú sí i láti ojú fèrèsé.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:27-35