Àwọn Ọba Keji 9:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jehu dé Jesireeli, Jesebẹli gbọ́; ó lé tìróò, ó di irun rẹ̀, ó sì ń yọjú wo ìta láti ojú fèrèsé ní òkè.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:26-32