Àwọn Ọba Keji 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu fi gbogbo agbára ta ọfà rẹ̀, ó bá Joramu lẹ́yìn, ó wọ inú ọkàn rẹ̀ lọ, Joramu sì kú sinu kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:14-26