Àwọn Ọba Keji 9:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Joramu bèèrè pé, “Ṣé alaafia ni?”Jehu dáhùn pé, “Alaafia ṣe lè wà níwọ̀n ìgbà tí ìwà àgbèrè ati àjẹ́ ìyá rẹ ṣì wà sibẹ.”

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:15-29