Àwọn Ọba Keji 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá tún rán oníṣẹ́ mìíràn lọ láti bèèrè ìbéèrè kan náà lọ́wọ́ Jehu. Ó tún dáhùn pé “Kí ni o fẹ́ fi alaafia ṣe? Bọ́ sẹ́yìn mi.”

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:16-29