Àwọn Ọba Keji 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu gun kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó lọ sí Jesireeli nítorí ibẹ̀ ni Joramu ọba wà, Ahasaya, ọba Juda sì wá bẹ̀ ẹ́ wò níbẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:11-17