Àwọn Ọba Keji 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́sẹ̀ kan náà, àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ tẹ́ aṣọ wọn sílẹ̀ fún un kí ó dúró lé, wọ́n sì fun fèrè pé, “Kabiyesi, Jehu ọba!”

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:12-18