Àwọn Ọba Keji 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa lọ sí Damasku ní àkókò kan tí Benhadadi ọba Siria wà lórí àìsàn. Nígbà tí wọ́n sọ fún ọba pé Eliṣa wà ní Damasku,

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:6-11