Àwọn Ọba Keji 8:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mejilelogun ni nígbà tí ó jọba ni Jerusalẹmu, ó sì jọba fún ọdún kan. Atalaya ni ìyá rẹ̀, ọmọ Omiri, ọba ilẹ̀ Israẹli.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:24-29