Àwọn Ọba Keji 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoramu kú, wọ́n sì sin ín sí ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi. Ahasaya ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:17-29