Àwọn Ọba Keji 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ìgbà náà ni Edomu ti di òmìnira kúrò lọ́wọ́ Juda. Ní àkókò kan náà ni ìlú Libina ṣọ̀tẹ̀ sí Juda.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:19-29