Àwọn Ọba Keji 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún karun-un tí Joramu ọmọ Ahabu jọba ní Israẹli, ni Jehoramu ọmọ Jehoṣafati jọba ní ilẹ̀ Juda.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:15-18