Àwọn Ọba Keji 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìgbà kan tí ọba Siria ń bá ọba Israẹli jagun, ó bá àwọn olórí ogun rẹ̀ gbèrò ibi tí wọn yóo ba sí de àwọn ọmọ ogun Israẹli.

Àwọn Ọba Keji 6

Àwọn Ọba Keji 6:1-9