Àwọn Ọba Keji 6:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́ ni ọba dé, ó ní, “Láti ọ̀dọ̀ OLUWA ni ibi yìí ti wá, kí ló dé tí n óo fi tún máa dúró de OLUWA fún ìrànlọ́wọ́?”

Àwọn Ọba Keji 6

Àwọn Ọba Keji 6:29-33