Àwọn Ọba Keji 6:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dáhùn pé, “Bí OLUWA kò bá ràn ọ́ lọ́wọ́, ìrànlọ́wọ́ wo ni èmi lè ṣe? Ṣé mo ní ìyẹ̀fun tabi ọtí waini ni?”

Àwọn Ọba Keji 6

Àwọn Ọba Keji 6:18-33