Àwọn Ọba Keji 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jọ̀wọ́ fún wa ní ààyè láti lọ gé igi ní etí odò Jọdani láti fi kọ́ ilé mìíràn tí a óo máa gbé.”Eliṣa dáhùn pé, “Ó dára, ẹ máa lọ.”

Àwọn Ọba Keji 6

Àwọn Ọba Keji 6:1-6