Àwọn Ọba Keji 6:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ pé, “Ẹ lọ wádìí ibi tí ó ń gbé, kí n lè ranṣẹ lọ mú un.”Nígbà tí wọ́n sọ fún un pé Eliṣa wà ní Dotani,

Àwọn Ọba Keji 6

Àwọn Ọba Keji 6:9-19