Àwọn Ọba Keji 5:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó wọlé, Eliṣa bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Níbo ni o lọ?”Ó dáhùn pé, “N kò lọ sí ibìkan kan.”

Àwọn Ọba Keji 5

Àwọn Ọba Keji 5:18-27