Àwọn Ọba Keji 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Eliṣa dáhùn pé, “Mo fi OLUWA tí mò ń sìn búra pé n kò ní gba nǹkankan lọ́wọ́ rẹ.”Naamani rọ̀ ọ́ kí ó gbà wọ́n, ṣugbọn ó kọ̀.

Àwọn Ọba Keji 5

Àwọn Ọba Keji 5:9-20