Àwọn Ọba Keji 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà lọ sinu ilé rẹ̀ pẹlu àwọn ọmọ rẹ̀, wọ́n sì ti ìlẹ̀kùn wọn; ó bá bẹ̀rẹ̀ sí da òróró náà sinu àwọn ìkòkò náà bí àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe ń gbé wọn wá.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:1-7