Àwọn Ọba Keji 4:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Iranṣẹ náà bá gbé oúnjẹ náà kalẹ̀ níwájú àwọn ọmọkunrin náà, wọ́n jẹ, ó sì ṣẹ́kù gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:38-44