Àwọn Ọba Keji 4:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà wólẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì dojúbolẹ̀. Lẹ́yìn náà, ó mú ọmọ rẹ̀, ó sì jáde lọ.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:35-44