Àwọn Ọba Keji 4:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ìyá ọmọ náà wí pé “Bí OLUWA tí ń bẹ láàyè tí ẹ̀mí ìwọ pàápàá sì ń bẹ, n kò ní fi ọ́ sílẹ̀.” Gehasi bá dìde, ó bá a lọ.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:29-32