Àwọn Ọba Keji 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa bèèrè pé, “Kí ni o fẹ́ kí n ṣe fún ọ? Sọ ohun tí o ní nílé fún mi.”Obinrin náà dáhùn pé, “N kò ní ohunkohun, àfi ìkòkò òróró kan.”

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:1-4