Àwọn Ọba Keji 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa bá bèèrè lọ́wọ́ Gehasi pé, “Kí ni mo lè ṣe fún un nígbà náà?”Gehasi ní, “Kò bímọ, ọkọ rẹ̀ sì ti di arúgbó.”

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:13-20