Àwọn Ọba Keji 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni Joramu, ati ọba Juda ati ọba Edomu bá gbéra láti lọ sójú ogun. Lẹ́yìn tí wọ́n ti rìn fún ọjọ́ meje, kò sí omi mímu mọ́ fún wọn ati fún àwọn ẹranko tí wọ́n ru ẹrù wọn.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:6-13