Àwọn Ọba Keji 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Meṣa, ọba Moabu, a máa sin aguntan; ní ọdọọdún, a máa fún ọba Israẹli ní ọ̀kẹ́ marun-un (100,000) ọ̀dọ́ aguntan ati irun ọ̀kẹ́ marun-un (100,000) àgbò, gẹ́gẹ́ bí ìṣákọ́lẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:1-11