Àwọn Ọba Keji 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba Moabu rí i pé ogun náà le pupọ, ó mú ẹẹdẹgbẹrin (700) ọkunrin tí wọ́n ń lo idà, ó gbìyànjú láti la ààrin ogun kọjá níwájú ọba Edomu, ṣugbọn kò ṣeéṣe.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:23-27